Jòhánù 7:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Jésù dá wọn lóhùn pé: “Ohun tí mo fi ń kọ́ni kì í ṣe tèmi, àmọ́ ó jẹ́ ti ẹni tó rán mi.+