ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Éfésù 5:5, 6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 5 Nítorí ẹ mọ èyí, ó sì ṣe kedere sí ẹ̀yin fúnra yín, pé kò sí oníṣekúṣe* kankan+ tàbí aláìmọ́ tàbí olójúkòkòrò,+ tó túmọ̀ sí jíjẹ́ abọ̀rìṣà, tí ó ní ogún èyíkéyìí nínú Ìjọba Kristi àti ti Ọlọ́run.+

      6 Ẹ má ṣe jẹ́ kí èèyàn kankan fi ọ̀rọ̀ asán tàn yín jẹ, ìdí ni pé torí irú àwọn nǹkan yìí ni ìrunú Ọlọ́run ṣe ń bọ̀ lórí àwọn ọmọ aláìgbọràn.

  • Hébérù 10:26, 27
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 26 Torí tí a bá mọ̀ọ́mọ̀ sọ ẹ̀ṣẹ̀ dàṣà lẹ́yìn tí a ti gba ìmọ̀ tó péye nípa òtítọ́,+ kò tún sí ẹbọ kankan fún ẹ̀ṣẹ̀ mọ́,+ 27 àfi ká máa fi ìbẹ̀rù retí ìdájọ́ àti ìbínú tó le, tó sì máa jó àwọn tó ń ṣàtakò run.+

Yorùbá Publications (1987-2026)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2026 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́