Jòhánù 3:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Lẹ́yìn èyí, Jésù àti àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ lọ sí ìgbèríko Jùdíà, ó lo àkókò díẹ̀ níbẹ̀ pẹ̀lú wọn, ó sì ń ṣe ìrìbọmi.+
22 Lẹ́yìn èyí, Jésù àti àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ lọ sí ìgbèríko Jùdíà, ó lo àkókò díẹ̀ níbẹ̀ pẹ̀lú wọn, ó sì ń ṣe ìrìbọmi.+