ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Mátíù 3:17
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 17 Wò ó! Ohùn kan tún dún láti ọ̀run+ pé: “Èyí ni Ọmọ mi,+ àyànfẹ́, ẹni tí mo ti tẹ́wọ́ gbà.”+

  • Máàkù 9:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 7 Ìkùukùu* wá kóra jọ, ó ṣíji bò wọ́n, ohùn kan+ sì dún látinú ìkùukùu náà pé: “Èyí ni Ọmọ mi, àyànfẹ́.+ Ẹ fetí sí i.”+

  • Jòhánù 12:28-30
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 28 Baba, ṣe orúkọ rẹ lógo.” Ni ohùn kan+ bá dún láti ọ̀run pé: “Mo ti ṣe é lógo, màá sì tún ṣe é lógo.”+

      29 Àwọn èrò tó dúró síbẹ̀ gbọ́, wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí í sọ pé ààrá ti sán. Àwọn míì sọ pé: “Áńgẹ́lì kan ti bá a sọ̀rọ̀.” 30 Jésù dáhùn pé: “Kì í ṣe torí tèmi ni ohùn yìí ṣe dún, torí tiyín ni.

  • 1 Jòhánù 5:9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 9 Tí a bá gba ẹ̀rí àwọn èèyàn, ẹ̀rí ti Ọlọ́run tóbi jù bẹ́ẹ̀ lọ. Torí ẹ̀rí tí Ọlọ́run fún wa nìyí, ẹ̀rí tó fún wa nípa Ọmọ rẹ̀.

Yorùbá Publications (1987-2026)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2026 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́