ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Mátíù 3:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 Nígbà yẹn, Jòhánù+ Arinibọmi wá, ó ń wàásù+ ní aginjù Jùdíà,

  • Mátíù 3:5, 6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 5 Àwọn èèyàn Jerúsálẹ́mù àti gbogbo Jùdíà àti gbogbo ìgbèríko tó yí Jọ́dánì ká máa ń lọ sọ́dọ̀ rẹ̀,+ 6 ó ń ṣèrìbọmi* fún wọn ní odò Jọ́dánì,+ wọ́n sì ń jẹ́wọ́ ẹ̀ṣẹ̀ wọn ní gbangba.

  • Máàkù 6:20
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 20 Hẹ́rọ́dù bẹ̀rù Jòhánù, ó mọ̀ pé olódodo ni, èèyàn mímọ́ sì ni,+ torí náà, ó ń dáàbò bò ó. Lẹ́yìn tó gbọ́ ọ̀rọ̀ rẹ̀, kò mọ ohun tó máa ṣe rárá, síbẹ̀ tayọ̀tayọ̀ ló máa ń gbọ́ ọ̀rọ̀ rẹ̀.

Yorùbá Publications (1987-2026)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2026 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́