-
Mátíù 14:22Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
22 Láìjáfara, ó mú kí àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ wọ ọkọ̀ ojú omi, kí wọ́n sì lọ ṣáájú rẹ̀ sí etíkun tó wà ní òdìkejì, ó sì ní kí àwọn èrò náà máa lọ.+
-