Jòhánù 6:64 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 64 Àmọ́ àwọn kan wà nínú yín tí kò gbà gbọ́.” Torí pé láti ìbẹ̀rẹ̀ ni Jésù ti mọ àwọn tí kò gbà gbọ́ àti ẹni tó máa dà á.+
64 Àmọ́ àwọn kan wà nínú yín tí kò gbà gbọ́.” Torí pé láti ìbẹ̀rẹ̀ ni Jésù ti mọ àwọn tí kò gbà gbọ́ àti ẹni tó máa dà á.+