Jòhánù 12:46 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 46 Mo wá sínú ayé bí ìmọ́lẹ̀,+ kí gbogbo ẹni tó bá ń ní ìgbàgbọ́ nínú mi má bàa wà nínú òkùnkùn.+ 1 Pétérù 2:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Àmọ́ ẹ̀yin ni “àwọn èèyàn tí Ọlọ́run yàn, ẹgbẹ́ àlùfáà aládé, orílẹ̀-èdè mímọ́,+ àwùjọ àwọn èèyàn tó jẹ́ ohun ìní pàtàkì,+ kí ẹ lè kéde káàkiri àwọn ọlá ńlá”*+ Ẹni tó pè yín jáde kúrò nínú òkùnkùn wá sínú ìmọ́lẹ̀ àgbàyanu rẹ̀.+ 1 Jòhánù 2:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Síbẹ̀, àṣẹ tuntun ni mò ń kọ̀wé rẹ̀ sí yín, ó jẹ́ òótọ́ nínú ọ̀rọ̀ tirẹ̀ àti nínú tiyín, torí òkùnkùn ń kọjá lọ, ìmọ́lẹ̀ tòótọ́ sì ti tàn báyìí.+
9 Àmọ́ ẹ̀yin ni “àwọn èèyàn tí Ọlọ́run yàn, ẹgbẹ́ àlùfáà aládé, orílẹ̀-èdè mímọ́,+ àwùjọ àwọn èèyàn tó jẹ́ ohun ìní pàtàkì,+ kí ẹ lè kéde káàkiri àwọn ọlá ńlá”*+ Ẹni tó pè yín jáde kúrò nínú òkùnkùn wá sínú ìmọ́lẹ̀ àgbàyanu rẹ̀.+
8 Síbẹ̀, àṣẹ tuntun ni mò ń kọ̀wé rẹ̀ sí yín, ó jẹ́ òótọ́ nínú ọ̀rọ̀ tirẹ̀ àti nínú tiyín, torí òkùnkùn ń kọjá lọ, ìmọ́lẹ̀ tòótọ́ sì ti tàn báyìí.+