Jòhánù 7:34 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 34 Ẹ máa wá mi, àmọ́ ẹ ò ní rí mi, ẹ ò sì ní lè wá sí ibi tí mo wà.”+ Jòhánù 13:33 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 33 Ẹ̀yin ọmọ kéékèèké, ìgbà díẹ̀ sí i ni màá fi wà pẹ̀lú yín. Ẹ máa wá mi; bí mo sì ṣe sọ fún àwọn Júù pé, ‘Ẹ ò lè wá sí ibi tí mò ń lọ,’+ mò ń sọ fún ẹ̀yin náà báyìí.
33 Ẹ̀yin ọmọ kéékèèké, ìgbà díẹ̀ sí i ni màá fi wà pẹ̀lú yín. Ẹ máa wá mi; bí mo sì ṣe sọ fún àwọn Júù pé, ‘Ẹ ò lè wá sí ibi tí mò ń lọ,’+ mò ń sọ fún ẹ̀yin náà báyìí.