1 Jòhánù 3:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Ẹni tó bá ń sọ ẹ̀ṣẹ̀ dàṣà wá látọ̀dọ̀ Èṣù, torí láti ìbẹ̀rẹ̀* ni Èṣù ti ń dẹ́ṣẹ̀.+ Ìdí tí a ṣe fi Ọmọ Ọlọ́run hàn kedere nìyí, kó lè fọ́ àwọn iṣẹ́ Èṣù túútúú.*+
8 Ẹni tó bá ń sọ ẹ̀ṣẹ̀ dàṣà wá látọ̀dọ̀ Èṣù, torí láti ìbẹ̀rẹ̀* ni Èṣù ti ń dẹ́ṣẹ̀.+ Ìdí tí a ṣe fi Ọmọ Ọlọ́run hàn kedere nìyí, kó lè fọ́ àwọn iṣẹ́ Èṣù túútúú.*+