ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Lúùkù 12:51
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 51 Ṣé ẹ rò pé mo wá láti mú kí àlàáfíà wà ní ayé ni? Rárá o, mò ń sọ fún yín pé, dípò ìyẹn, ìpínyà ni.+

  • Jòhánù 7:12
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 12 Ọ̀pọ̀ èèyàn ń sọ̀rọ̀ kẹ́lẹ́kẹ́lẹ́ nípa rẹ̀ láàárín èrò. Àwọn kan á sọ pé: “Èèyàn dáadáa ni.” Àwọn míì á sọ pé: “Irọ́ ni. Ṣe ló ń tan àwọn èèyàn jẹ.”+

  • Jòhánù 7:43
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 43 Àwọn èrò náà wá pínyà síra wọn nítorí rẹ̀.

  • Jòhánù 10:19
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 19 Àwọn Júù tún pínyà síra wọn+ nítorí àwọn ọ̀rọ̀ yìí.

Yorùbá Publications (1987-2026)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2026 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́