Mátíù 26:31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 Jésù sọ fún wọn pé: “Gbogbo yín lẹ máa kọsẹ̀ torí ohun tó máa ṣẹlẹ̀ sí mi lóru òní, torí a ti kọ ọ́ pé: ‘Màá kọ lu olùṣọ́ àgùntàn, àwọn àgùntàn inú agbo sì máa tú ká.’+ Máàkù 14:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Jésù sì sọ fún wọn pé: “Gbogbo yín lẹ máa kọsẹ̀, torí a ti kọ ọ́ pé: ‘Màá kọ lu olùṣọ́ àgùntàn,+ àwọn àgùntàn sì máa tú ká.’+ Jòhánù 10:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Èmi ni olùṣọ́ àgùntàn àtàtà;+ olùṣọ́ àgùntàn àtàtà máa ń fi ẹ̀mí* rẹ̀ lélẹ̀ nítorí àwọn àgùntàn.+
31 Jésù sọ fún wọn pé: “Gbogbo yín lẹ máa kọsẹ̀ torí ohun tó máa ṣẹlẹ̀ sí mi lóru òní, torí a ti kọ ọ́ pé: ‘Màá kọ lu olùṣọ́ àgùntàn, àwọn àgùntàn inú agbo sì máa tú ká.’+
27 Jésù sì sọ fún wọn pé: “Gbogbo yín lẹ máa kọsẹ̀, torí a ti kọ ọ́ pé: ‘Màá kọ lu olùṣọ́ àgùntàn,+ àwọn àgùntàn sì máa tú ká.’+