-
Lúùkù 22:48Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
48 Àmọ́ Jésù sọ fún un pé: “Júdásì, ṣé o fẹ́ fi ẹnu ko Ọmọ èèyàn lẹ́nu kí o lè dalẹ̀ rẹ̀ ni?”
-
-
Jòhánù 13:29Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
29 Àwọn kan tiẹ̀ ń rò pé torí pé ọwọ́ Júdásì ni àpótí owó wà,+ ṣe ni Jésù ń sọ fún un pé, “Ra àwọn nǹkan tí a máa fi ṣe àjọyọ̀ náà” tàbí pé kó fún àwọn aláìní ní nǹkan.
-