ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Mátíù 26:12
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 12 Nígbà tí obìnrin yìí da òróró onílọ́fínńdà yìí sí ara mi, ó ṣe é kó lè múra mi sílẹ̀ fún ìsìnkú.+

  • Máàkù 14:8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 8 Ó ṣe ohun tó lè ṣe; ó da òróró onílọ́fínńdà sí ara mi ṣáájú nítorí ìsìnkú.+

  • Jòhánù 19:40
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 40 Torí náà, wọ́n gbé òkú Jésù, wọ́n sì fi aṣọ ọ̀gbọ̀* dì í pẹ̀lú àwọn èròjà tó ń ta sánsán náà,+ bí àwọn Júù ṣe máa ń sìnkú.

Yorùbá Publications (1987-2026)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2026 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́