Jòhánù 14:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Jésù sọ fún un pé: “Fílípì, pẹ̀lú bó ṣe pẹ́ tó tí mo ti wà pẹ̀lú yín, ṣé o ò tíì mọ̀ mí ni? Ẹnikẹ́ni tó bá ti rí mi ti rí Baba náà.+ Kí ló dé tí o wá sọ pé, ‘Fi Baba hàn wá’?
9 Jésù sọ fún un pé: “Fílípì, pẹ̀lú bó ṣe pẹ́ tó tí mo ti wà pẹ̀lú yín, ṣé o ò tíì mọ̀ mí ni? Ẹnikẹ́ni tó bá ti rí mi ti rí Baba náà.+ Kí ló dé tí o wá sọ pé, ‘Fi Baba hàn wá’?