Jòhánù 8:38 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 38 Mò ń sọ àwọn ohun tí mo ti rí nígbà tí mo wà lọ́dọ̀ Baba mi,+ àmọ́ ohun tí ẹ̀yin gbọ́ látọ̀dọ̀ bàbá yín lẹ̀ ń ṣe.” Jòhánù 14:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ṣé o ò gbà pé mo wà ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú Baba àti pé Baba wà ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú mi ni?+ Kì í ṣe èrò ara mi+ ni àwọn nǹkan tí mò ń sọ fún yín, àmọ́ Baba tó ṣì wà ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú mi ló ń ṣe àwọn iṣẹ́ rẹ̀.
38 Mò ń sọ àwọn ohun tí mo ti rí nígbà tí mo wà lọ́dọ̀ Baba mi,+ àmọ́ ohun tí ẹ̀yin gbọ́ látọ̀dọ̀ bàbá yín lẹ̀ ń ṣe.”
10 Ṣé o ò gbà pé mo wà ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú Baba àti pé Baba wà ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú mi ni?+ Kì í ṣe èrò ara mi+ ni àwọn nǹkan tí mò ń sọ fún yín, àmọ́ Baba tó ṣì wà ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú mi ló ń ṣe àwọn iṣẹ́ rẹ̀.