Fílípì 2:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ẹ ní èrò yìí nínú yín, irú èyí tí Kristi Jésù náà ní,+ 1 Pétérù 2:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Kódà, ọ̀nà yìí la pè yín sí, torí Kristi pàápàá jìyà torí yín,+ ó fi àpẹẹrẹ lélẹ̀ fún yín kí ẹ lè máa tọ ipasẹ̀ rẹ̀ pẹ́kípẹ́kí.+ 1 Jòhánù 2:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ẹni tó bá sọ pé òun wà ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú rẹ̀, òun fúnra rẹ̀ gbọ́dọ̀ máa rìn bí ẹni yẹn ṣe rìn.+
21 Kódà, ọ̀nà yìí la pè yín sí, torí Kristi pàápàá jìyà torí yín,+ ó fi àpẹẹrẹ lélẹ̀ fún yín kí ẹ lè máa tọ ipasẹ̀ rẹ̀ pẹ́kípẹ́kí.+