Lúùkù 22:3, 4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Sátánì wá wọnú Júdásì, tí wọ́n ń pè ní Ìsìkáríọ́tù, tó wà lára àwọn Méjìlá náà,+ 4 ó sì lọ bá àwọn olórí àlùfáà àti àwọn olórí ẹ̀ṣọ́ tẹ́ńpìlì sọ̀rọ̀ nípa bó ṣe máa fà á lé wọn lọ́wọ́.+
3 Sátánì wá wọnú Júdásì, tí wọ́n ń pè ní Ìsìkáríọ́tù, tó wà lára àwọn Méjìlá náà,+ 4 ó sì lọ bá àwọn olórí àlùfáà àti àwọn olórí ẹ̀ṣọ́ tẹ́ńpìlì sọ̀rọ̀ nípa bó ṣe máa fà á lé wọn lọ́wọ́.+