Mátíù 13:55 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 55 Àbí ọmọ káfíńtà kọ́ nìyí?+ Ṣebí Màríà lorúkọ ìyá rẹ̀, Jémíìsì, Jósẹ́fù, Símónì àti Júdásì sì ni àwọn arákùnrin rẹ̀?+ Máàkù 3:31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 Ìyá rẹ̀ àti àwọn arákùnrin rẹ̀+ wá, wọ́n dúró síta, wọ́n sì ní kí ẹnì kan lọ pè é wá.+ Lúùkù 8:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Ìyá rẹ̀ àti àwọn arákùnrin rẹ̀+ wá a wá, àmọ́ wọn ò ráyè dé ọ̀dọ̀ rẹ̀ torí èrò wà níbẹ̀.+ Ìṣe 1:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Gbogbo wọn tẹra mọ́ àdúrà pẹ̀lú èrò tó ṣọ̀kan, àwọn àti àwọn obìnrin kan+ pẹ̀lú Màríà ìyá Jésù àti àwọn arákùnrin rẹ̀.+
55 Àbí ọmọ káfíńtà kọ́ nìyí?+ Ṣebí Màríà lorúkọ ìyá rẹ̀, Jémíìsì, Jósẹ́fù, Símónì àti Júdásì sì ni àwọn arákùnrin rẹ̀?+
14 Gbogbo wọn tẹra mọ́ àdúrà pẹ̀lú èrò tó ṣọ̀kan, àwọn àti àwọn obìnrin kan+ pẹ̀lú Màríà ìyá Jésù àti àwọn arákùnrin rẹ̀.+