47 Bó ṣe ń sọ̀rọ̀ lọ́wọ́, wò ó! Júdásì, ọ̀kan lára àwọn Méjìlá náà dé pẹ̀lú èrò rẹpẹtẹ tí wọ́n kó idà àti kùmọ̀ dání, àwọn olórí àlùfáà àti àwọn àgbààgbà àwọn èèyàn náà ló rán wọn wá.+
43 Lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀, bó ṣe ń sọ̀rọ̀ lọ́wọ́, Júdásì, ọ̀kan lára àwọn Méjìlá náà dé pẹ̀lú èrò tí wọ́n kó idà àti kùmọ̀ dání, àwọn olórí àlùfáà, àwọn akọ̀wé òfin àti àwọn àgbààgbà ló rán wọn wá.+