Mátíù 27:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Pílátù sọ fún wọn pé: “Kí wá ni kí n ṣe sí Jésù tí wọ́n ń pè ní Kristi?” Gbogbo wọ́n sọ pé: “Kàn án mọ́gi!”*+ Máàkù 15:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Wọ́n ké jáde lẹ́ẹ̀kan sí i pé: “Kàn án mọ́gi!”*+ Lúùkù 23:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Wọ́n wá bẹ̀rẹ̀ sí í pariwo pé: “Kàn án mọ́gi! Kàn án mọ́gi!”*+
22 Pílátù sọ fún wọn pé: “Kí wá ni kí n ṣe sí Jésù tí wọ́n ń pè ní Kristi?” Gbogbo wọ́n sọ pé: “Kàn án mọ́gi!”*+