-
Mátíù 27:61Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
61 Àmọ́ Màríà Magidalénì àti Màríà kejì ò kúrò níbẹ̀, wọ́n jókòó síwájú sàréè náà.+
-
-
Máàkù 15:40Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
40 Àwọn obìnrin kan tún wà, tí wọ́n ń wòran láti ọ̀ọ́kán, lára wọn ni Màríà Magidalénì, Màríà ìyá Jémíìsì Kékeré àti Jósè àti Sàlómẹ̀,+
-
-
Lúùkù 23:49Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
49 Gbogbo àwọn tó mọ̀ ọ́n sì dúró ní ọ̀ọ́kán. Bákan náà, àwọn obìnrin tó tẹ̀ lé e láti Gálílì wà níbẹ̀, wọ́n rí àwọn nǹkan yìí.+
-