ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sekaráyà 12:10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 “Màá tú ẹ̀mí ojú rere àti ìrawọ́ ẹ̀bẹ̀ sórí ilé Dáfídì àti àwọn tó ń gbé Jerúsálẹ́mù, wọ́n máa wo ẹni tí wọ́n gún,+ wọ́n sì máa pohùn réré ẹkún torí rẹ̀ bí ìgbà tí wọ́n ń sunkún torí ọmọkùnrin kan ṣoṣo; wọ́n sì máa ṣọ̀fọ̀ gan-an torí rẹ̀ bí ìgbà tí wọ́n ń ṣọ̀fọ̀ torí àkọ́bí ọmọkùnrin.

  • Ìfihàn 1:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 7 Wò ó! Ó ń bọ̀ pẹ̀lú ìkùukùu,*+ gbogbo ojú sì máa rí i, títí kan àwọn tó gún un lọ́kọ̀; ìbànújẹ́ nítorí rẹ̀ sì máa mú kí gbogbo ẹ̀yà tó wà ní ayé lu ara wọn.+ Bẹ́ẹ̀ ni kó rí, Àmín.

Yorùbá Publications (1987-2026)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2026 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́