Jòhánù 8:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Torí náà, Jésù sọ pé: “Lẹ́yìn tí ẹ bá ti gbé Ọmọ èèyàn sókè,+ ìgbà yẹn lẹ máa wá mọ̀ pé èmi ni+ àti pé mi ò dá ṣe nǹkan kan lérò ara mi;+ àmọ́ bí Baba ṣe kọ́ mi gẹ́lẹ́ ni mò ń sọ àwọn nǹkan yìí. Gálátíà 3:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Kristi rà wá,+ ó tú wa sílẹ̀+ lábẹ́ ègún Òfin bó ṣe di ẹni ègún dípò wa, nítorí ó wà lákọsílẹ̀ pé: “Ẹni ègún ni ẹni tí a gbé kọ́ sórí òpó igi.”+
28 Torí náà, Jésù sọ pé: “Lẹ́yìn tí ẹ bá ti gbé Ọmọ èèyàn sókè,+ ìgbà yẹn lẹ máa wá mọ̀ pé èmi ni+ àti pé mi ò dá ṣe nǹkan kan lérò ara mi;+ àmọ́ bí Baba ṣe kọ́ mi gẹ́lẹ́ ni mò ń sọ àwọn nǹkan yìí.
13 Kristi rà wá,+ ó tú wa sílẹ̀+ lábẹ́ ègún Òfin bó ṣe di ẹni ègún dípò wa, nítorí ó wà lákọsílẹ̀ pé: “Ẹni ègún ni ẹni tí a gbé kọ́ sórí òpó igi.”+