Jòhánù 11:47 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 47 Torí náà, àwọn olórí àlùfáà àti àwọn Farisí kó Sàhẹ́ndìrìn jọ, wọ́n sì sọ pé: “Kí ni ká ṣe, torí ọkùnrin yìí ń ṣe ọ̀pọ̀ iṣẹ́ àmì?+
47 Torí náà, àwọn olórí àlùfáà àti àwọn Farisí kó Sàhẹ́ndìrìn jọ, wọ́n sì sọ pé: “Kí ni ká ṣe, torí ọkùnrin yìí ń ṣe ọ̀pọ̀ iṣẹ́ àmì?+