Ìṣe 3:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 ẹ wá pa Olórí Aṣojú ìyè.+ Àmọ́ Ọlọ́run gbé e dìde kúrò nínú ikú, òtítọ́ yìí ni àwa ń jẹ́rìí sí.+