34 Ní ti tòótọ́, kò sẹ́ni tó ṣaláìní láàárín wọn,+ torí ṣe ni gbogbo àwọn tó ní ilẹ̀ tàbí ilé ń tà wọ́n, tí wọ́n sì ń mú owó ohun tí wọ́n tà wá, 35 wọ́n á sì fi sílẹ̀ lẹ́gbẹ̀ẹ́ ẹsẹ̀ àwọn àpọ́sítélì.+ Àwọn náà á wá pín in fún ẹnì kọ̀ọ̀kan bí ohun tó nílò bá ṣe pọ̀ tó.+