Lúùkù 8:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Kò pẹ́ lẹ́yìn náà, ó ń rin ìrìn àjò láti ìlú dé ìlú àti láti abúlé dé abúlé, ó ń wàásù, ó sì ń polongo ìhìn rere Ìjọba Ọlọ́run.+ Àwọn Méjìlá náà sì wà pẹ̀lú rẹ̀,
8 Kò pẹ́ lẹ́yìn náà, ó ń rin ìrìn àjò láti ìlú dé ìlú àti láti abúlé dé abúlé, ó ń wàásù, ó sì ń polongo ìhìn rere Ìjọba Ọlọ́run.+ Àwọn Méjìlá náà sì wà pẹ̀lú rẹ̀,