Ìṣe 4:36, 37 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 36 Nítorí náà, Jósẹ́fù, tí àwọn àpọ́sítélì tún ń pè ní Bánábà+ (tó túmọ̀ sí “Ọmọ Ìtùnú”, nígbà tí a bá túmọ̀ rẹ̀), tó jẹ́ ọmọ Léfì, ọmọ ìbílẹ̀ Sápírọ́sì, 37 ní ilẹ̀ kan, ó tà á, ó sì mú owó náà wá, ó sì fi sílẹ̀ lẹ́gbẹ̀ẹ́ ẹsẹ̀ àwọn àpọ́sítélì.+
36 Nítorí náà, Jósẹ́fù, tí àwọn àpọ́sítélì tún ń pè ní Bánábà+ (tó túmọ̀ sí “Ọmọ Ìtùnú”, nígbà tí a bá túmọ̀ rẹ̀), tó jẹ́ ọmọ Léfì, ọmọ ìbílẹ̀ Sápírọ́sì, 37 ní ilẹ̀ kan, ó tà á, ó sì mú owó náà wá, ó sì fi sílẹ̀ lẹ́gbẹ̀ẹ́ ẹsẹ̀ àwọn àpọ́sítélì.+