Lúùkù 24:30, 31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 30 Bó ṣe ń bá wọn jẹun,* ó mú búrẹ́dì, ó súre sí i, ó bù ú, ó sì bẹ̀rẹ̀ sí í fún wọn.+ 31 Ìgbà yẹn ni ojú wọn là rekete, wọ́n sì dá a mọ̀; àmọ́ ó pòórá láàárín wọn.+ Jòhánù 21:13, 14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Jésù wá, ó mú búrẹ́dì náà, ó sì fún wọn, ó ṣe bẹ́ẹ̀ náà sí ẹja. 14 Ìgbà kẹta nìyí+ tí Jésù fara han àwọn ọmọ ẹ̀yìn lẹ́yìn tó jíǹde.
30 Bó ṣe ń bá wọn jẹun,* ó mú búrẹ́dì, ó súre sí i, ó bù ú, ó sì bẹ̀rẹ̀ sí í fún wọn.+ 31 Ìgbà yẹn ni ojú wọn là rekete, wọ́n sì dá a mọ̀; àmọ́ ó pòórá láàárín wọn.+
13 Jésù wá, ó mú búrẹ́dì náà, ó sì fún wọn, ó ṣe bẹ́ẹ̀ náà sí ẹja. 14 Ìgbà kẹta nìyí+ tí Jésù fara han àwọn ọmọ ẹ̀yìn lẹ́yìn tó jíǹde.