-
Ìṣe 14:21, 22Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
21 Lẹ́yìn tí wọ́n kéde ìhìn rere fún ìlú yẹn, tí wọ́n sì sọ àwọn díẹ̀ di ọmọ ẹ̀yìn, wọ́n pa dà sí Lísírà, Íkóníónì àti Áńtíókù. 22 Nígbà tí wọ́n débẹ̀, wọ́n fún àwọn ọmọ ẹ̀yìn* lókun,+ wọ́n fún wọn ní ìṣírí láti má ṣe kúrò nínú ìgbàgbọ́, wọ́n sì sọ pé: “A gbọ́dọ̀ ti inú ọ̀pọ̀ ìpọ́njú wọ Ìjọba Ọlọ́run.”+
-