-
1 Pétérù 2:9, 10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 Àmọ́ ẹ̀yin ni “àwọn èèyàn tí Ọlọ́run yàn, ẹgbẹ́ àlùfáà aládé, orílẹ̀-èdè mímọ́,+ àwùjọ àwọn èèyàn tó jẹ́ ohun ìní pàtàkì,+ kí ẹ lè kéde káàkiri àwọn ọlá ńlá”*+ Ẹni tó pè yín jáde kúrò nínú òkùnkùn wá sínú ìmọ́lẹ̀ àgbàyanu rẹ̀.+ 10 Torí ẹ kì í ṣe àwùjọ èèyàn nígbà kan, àmọ́ ní báyìí ẹ ti di àwùjọ èèyàn Ọlọ́run;+ a kò ṣàánú yín nígbà kan, àmọ́ ní báyìí, a ti ṣàánú yín.+
-