Jòhánù 16:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Àmọ́ tí ìyẹn* bá dé, ẹ̀mí òtítọ́,+ ó máa darí yín sínú gbogbo òtítọ́, torí kì í ṣe èrò ara rẹ̀ ló máa sọ, àmọ́ ohun tó gbọ́ ló máa sọ, ó sì máa kéde àwọn nǹkan tó ń bọ̀ fún yín.+ Ìṣe 5:32 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 32 Àwa ni ẹlẹ́rìí àwọn nǹkan yìí,+ bẹ́ẹ̀ sì ni ẹ̀mí mímọ́,+ èyí tí Ọlọ́run fún àwọn tó ń ṣègbọràn sí i gẹ́gẹ́ bí alákòóso.”
13 Àmọ́ tí ìyẹn* bá dé, ẹ̀mí òtítọ́,+ ó máa darí yín sínú gbogbo òtítọ́, torí kì í ṣe èrò ara rẹ̀ ló máa sọ, àmọ́ ohun tó gbọ́ ló máa sọ, ó sì máa kéde àwọn nǹkan tó ń bọ̀ fún yín.+
32 Àwa ni ẹlẹ́rìí àwọn nǹkan yìí,+ bẹ́ẹ̀ sì ni ẹ̀mí mímọ́,+ èyí tí Ọlọ́run fún àwọn tó ń ṣègbọràn sí i gẹ́gẹ́ bí alákòóso.”