Ìṣe 16:1, 2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Nítorí náà, Pọ́ọ̀lù dé Déébè, ó sì dé Lísírà.+ Ọmọ ẹ̀yìn kan wà níbẹ̀ tó ń jẹ́ Tímótì,+ ọmọkùnrin obìnrin Júù kan tó jẹ́ onígbàgbọ́, àmọ́ Gíríìkì ni bàbá rẹ̀, 2 àwọn ará ní Lísírà àti Íkóníónì sì ròyìn rẹ̀ dáadáa. 1 Tẹsalóníkà 3:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 a sì rán Tímótì,+ arákùnrin wa àti òjíṣẹ́* Ọlọ́run nínú ìhìn rere nípa Kristi, kí ó lè mú kí ẹ fìdí múlẹ̀,* kí ó sì tù yín nínú nítorí ìgbàgbọ́ yín,
16 Nítorí náà, Pọ́ọ̀lù dé Déébè, ó sì dé Lísírà.+ Ọmọ ẹ̀yìn kan wà níbẹ̀ tó ń jẹ́ Tímótì,+ ọmọkùnrin obìnrin Júù kan tó jẹ́ onígbàgbọ́, àmọ́ Gíríìkì ni bàbá rẹ̀, 2 àwọn ará ní Lísírà àti Íkóníónì sì ròyìn rẹ̀ dáadáa.
2 a sì rán Tímótì,+ arákùnrin wa àti òjíṣẹ́* Ọlọ́run nínú ìhìn rere nípa Kristi, kí ó lè mú kí ẹ fìdí múlẹ̀,* kí ó sì tù yín nínú nítorí ìgbàgbọ́ yín,