-
Ìṣe 18:24, 25Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
24 Júù kan wà tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Àpólò,+ ọmọ ìbílẹ̀ Alẹkisáńdíríà, ó dé sí Éfésù; ọkùnrin sọ̀rọ̀sọ̀rọ̀ tó mọ Ìwé Mímọ́ dunjú ni. 25 Ọkùnrin yìí ti gba ẹ̀kọ́* nípa ọ̀nà Jèhófà,* iná ẹ̀mí sì ń jó nínú rẹ̀, ó ń sọ̀rọ̀, ó sì ń kọ́ni ní àwọn nǹkan tó jẹ mọ́ Jésù lọ́nà tó péye, àmọ́ ìrìbọmi Jòhánù nìkan ló mọ̀.
-