-
Kólósè 1:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 tó dé ọ̀dọ̀ yín. Bí ìhìn rere náà ṣe ń so èso, tó sì ń gbilẹ̀ ní gbogbo ayé,+ bẹ́ẹ̀ náà ló ń ṣe láàárín yín láti ọjọ́ tí ẹ ti gbọ́, tí ẹ sì ti mọ inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí Ọlọ́run ní òtítọ́ àti lọ́nà tó péye.
-