-
Ìṣe 23:12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
12 Nígbà tí ilẹ̀ mọ́, àwọn Júù gbìmọ̀ pọ̀, wọ́n sì fi ègún de ara wọn, pé àwọn ò ní jẹ, àwọn ò sì ní mu títí àwọn á fi pa Pọ́ọ̀lù.
-
-
Ìṣe 23:16Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
16 Ṣùgbọ́n, ọmọ arábìnrin Pọ́ọ̀lù gbọ́ pé wọ́n fẹ́ lúgọ de Pọ́ọ̀lù, ló bá wọ ibùdó àwọn ọmọ ogun, ó sì sọ fún Pọ́ọ̀lù.
-