Jòhánù 14:16, 17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Màá béèrè lọ́wọ́ Baba, ó sì máa fún yín ní olùrànlọ́wọ́* míì tó máa wà pẹ̀lú yín títí láé,+ 17 ẹ̀mí òtítọ́,+ tí ayé ò lè gbà, torí pé kò rí i, kò sì mọ̀ ọ́n.+ Ẹ̀yin mọ̀ ọ́n, torí ó wà pẹ̀lú yín, ó sì wà nínú yín. Ìṣe 2:33 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 33 Tóò, nítorí pé a gbé e ga sí ọwọ́ ọ̀tún Ọlọ́run,+ tí ó sì gba ẹ̀mí mímọ́ tí Baba ṣèlérí,+ ó tú ohun tí ẹ rí, tí ẹ sì gbọ́ jáde.
16 Màá béèrè lọ́wọ́ Baba, ó sì máa fún yín ní olùrànlọ́wọ́* míì tó máa wà pẹ̀lú yín títí láé,+ 17 ẹ̀mí òtítọ́,+ tí ayé ò lè gbà, torí pé kò rí i, kò sì mọ̀ ọ́n.+ Ẹ̀yin mọ̀ ọ́n, torí ó wà pẹ̀lú yín, ó sì wà nínú yín.
33 Tóò, nítorí pé a gbé e ga sí ọwọ́ ọ̀tún Ọlọ́run,+ tí ó sì gba ẹ̀mí mímọ́ tí Baba ṣèlérí,+ ó tú ohun tí ẹ rí, tí ẹ sì gbọ́ jáde.