Ìṣe 15:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Àwọn ọkùnrin kan wá láti Jùdíà, wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí í kọ́ àwọn ará pé: “Láìjẹ́ pé ẹ dádọ̀dọ́* gẹ́gẹ́ bí àṣà tí Mósè fi lélẹ̀,+ ẹ ò lè rí ìgbàlà.”
15 Àwọn ọkùnrin kan wá láti Jùdíà, wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí í kọ́ àwọn ará pé: “Láìjẹ́ pé ẹ dádọ̀dọ́* gẹ́gẹ́ bí àṣà tí Mósè fi lélẹ̀,+ ẹ ò lè rí ìgbàlà.”