Ìṣe 20:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Àwọn tó bá a lọ ni Sópátérì ọmọ Párù ará Bèróà, Àrísítákọ́sì+ àti Sẹ́kúńdù láti Tẹsalóníkà, Gáyọ́sì ará Déébè, Tímótì+ pẹ̀lú Tíkíkù+ àti Tírófímù+ láti ìpínlẹ̀ Éṣíà. 2 Tímótì 4:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Érásítù+ dúró sí Kọ́ríńtì, àmọ́ mo fi Tírófímù+ sílẹ̀ ní Mílétù, ara rẹ̀ ò yá.
4 Àwọn tó bá a lọ ni Sópátérì ọmọ Párù ará Bèróà, Àrísítákọ́sì+ àti Sẹ́kúńdù láti Tẹsalóníkà, Gáyọ́sì ará Déébè, Tímótì+ pẹ̀lú Tíkíkù+ àti Tírófímù+ láti ìpínlẹ̀ Éṣíà.