Ìṣe 8:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ṣùgbọ́n Sọ́ọ̀lù bẹ̀rẹ̀ sí í hùwà ìkà sí ìjọ. Bó ṣe ń jáde nínú ilé kan ló ń wọ òmíì, ó ń wọ́ tọkùnrin tobìnrin jáde, ó sì ń jù wọ́n sẹ́wọ̀n.+
3 Ṣùgbọ́n Sọ́ọ̀lù bẹ̀rẹ̀ sí í hùwà ìkà sí ìjọ. Bó ṣe ń jáde nínú ilé kan ló ń wọ òmíì, ó ń wọ́ tọkùnrin tobìnrin jáde, ó sì ń jù wọ́n sẹ́wọ̀n.+