ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ìṣe 26:4, 5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 “Ní tòótọ́, irú ìgbésí ayé tí mo gbé láti ìgbà èwe mi láàárín àwọn èèyàn* mi àti ní Jerúsálẹ́mù ni gbogbo àwọn Júù mọ̀ dáadáa,+ 5 ìyẹn àwọn tó ti mọ̀ mí tipẹ́tipẹ́, tí wọ́n bá fẹ́, wọ́n lè jẹ́rìí sí i pé ìgbé ayé Farisí ni mo gbé+ ní ìlànà ẹ̀ya ìsìn tí kò gba gbẹ̀rẹ́ rárá,+ ti ọ̀nà ìjọsìn wa.

  • Fílípì 3:4, 5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 torí náà, tí a bá rí ẹnikẹ́ni tó ní ìdí láti gbẹ́kẹ̀ lé ẹran ara, èmi gan-an ní.

      Tí ẹlòmíì bá sì rò pé òun ní ìdí láti gbẹ́kẹ̀ lé ẹran ara, tèmi jù bẹ́ẹ̀: 5 mo dádọ̀dọ́* ní ọjọ́ kẹjọ,+ mo jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Ísírẹ́lì, mo wá láti ẹ̀yà Bẹ́ńjámínì, Hébérù tó jẹ́ ọmọ bíbí àwọn Hébérù;+ ní ti òfin, mo jẹ́ Farisí;+

Yorùbá Publications (1987-2026)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2026 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́