-
Ìṣe 24:11, 12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 Ìwọ fúnra rẹ lè wádìí, kò tíì ju ọjọ́ méjìlá (12) tí mo lọ jọ́sìn ní Jerúsálẹ́mù;+ 12 wọn ò sì rí mi pé mò ń bá èèyàn jiyàn nínú tẹ́ńpìlì, àbí pé mo dá àwùjọ onírúgúdù sílẹ̀, yálà nínú àwọn sínágọ́gù tàbí káàkiri ìlú náà.
-