Lúùkù 24:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Ó wá bẹ̀rẹ̀ látọ̀dọ̀ Mósè àti gbogbo àwọn Wòlíì,+ ó sì túmọ̀ àwọn nǹkan tó jẹ mọ́ òun fúnra rẹ̀ nínú gbogbo Ìwé Mímọ́ fún wọn. Lúùkù 24:44 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 44 Lẹ́yìn náà, ó sọ fún wọn pé: “Àwọn ọ̀rọ̀ tí mo bá yín sọ nìyí, nígbà tí mo ṣì wà lọ́dọ̀ yín,+ pé gbogbo ohun tí a kọ nípa mi nínú Òfin Mósè àti nínú ìwé àwọn Wòlíì àti Sáàmù gbọ́dọ̀ ṣẹ.”+ Róòmù 3:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Àmọ́ ní báyìí, láìgbára lé òfin, a ti fi òdodo Ọlọ́run hàn,+ bí Òfin àti àwọn Wòlíì ṣe jẹ́rìí sí i,+
27 Ó wá bẹ̀rẹ̀ látọ̀dọ̀ Mósè àti gbogbo àwọn Wòlíì,+ ó sì túmọ̀ àwọn nǹkan tó jẹ mọ́ òun fúnra rẹ̀ nínú gbogbo Ìwé Mímọ́ fún wọn.
44 Lẹ́yìn náà, ó sọ fún wọn pé: “Àwọn ọ̀rọ̀ tí mo bá yín sọ nìyí, nígbà tí mo ṣì wà lọ́dọ̀ yín,+ pé gbogbo ohun tí a kọ nípa mi nínú Òfin Mósè àti nínú ìwé àwọn Wòlíì àti Sáàmù gbọ́dọ̀ ṣẹ.”+
21 Àmọ́ ní báyìí, láìgbára lé òfin, a ti fi òdodo Ọlọ́run hàn,+ bí Òfin àti àwọn Wòlíì ṣe jẹ́rìí sí i,+