-
Ìṣe 4:34Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
34 Ní ti tòótọ́, kò sẹ́ni tó ṣaláìní láàárín wọn,+ torí ṣe ni gbogbo àwọn tó ní ilẹ̀ tàbí ilé ń tà wọ́n, tí wọ́n sì ń mú owó ohun tí wọ́n tà wá,
-