2 Kọ́ríńtì 1:3, 4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ìyìn ni fún Ọlọ́run àti Baba Olúwa wa Jésù Kristi,+ Baba àánú oníjẹ̀lẹ́ńkẹ́+ àti Ọlọ́run ìtùnú gbogbo,+ 4 ẹni tó ń tù wá nínú* nínú gbogbo àdánwò* wa,+ kí a lè fi ìtùnú tí a gbà lọ́dọ̀ rẹ̀+ tu àwọn míì nínú+ lábẹ́ àdánwò* èyíkéyìí tí wọ́n bá wà.
3 Ìyìn ni fún Ọlọ́run àti Baba Olúwa wa Jésù Kristi,+ Baba àánú oníjẹ̀lẹ́ńkẹ́+ àti Ọlọ́run ìtùnú gbogbo,+ 4 ẹni tó ń tù wá nínú* nínú gbogbo àdánwò* wa,+ kí a lè fi ìtùnú tí a gbà lọ́dọ̀ rẹ̀+ tu àwọn míì nínú+ lábẹ́ àdánwò* èyíkéyìí tí wọ́n bá wà.