ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ìṣe 23:26
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 26 “Kíláúdíù Lísíà sí Ọlọ́lá Jù Lọ, Gómìnà Fẹ́líìsì: Mo kí ọ!

  • Ìṣe 23:29
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 29 Mo rí i pé wọ́n fẹ̀sùn kàn án lórí àwọn ọ̀ràn Òfin wọn,+ àmọ́ kò ṣe ohunkóhun tó yẹ fún ikú tàbí fún ìdè.

  • Ìṣe 25:24, 25
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 24 Fẹ́sítọ́ọ̀sì wá sọ pé: “Ọba Ágírípà àti gbogbo ẹ̀yin tí ẹ wà pẹ̀lú wa, ọkùnrin tí ẹ̀ ń wò yìí ni gbogbo àwọn Júù tó wà ní Jerúsálẹ́mù àti níbí yìí fi ẹjọ́ rẹ̀ sùn mí, tí wọ́n ń kígbe pé kò yẹ kó wà láàyè mọ́.+ 25 Àmọ́ mo rí i pé kò ṣe nǹkan kan tó yẹ fún ikú.+ Torí náà, nígbà tí ọkùnrin yìí fúnra rẹ̀ ké gbàjarè sí Ẹni Ọlọ́lá, mo pinnu pé màá rán an lọ.

  • Ìṣe 26:31, 32
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 31 Àmọ́ bí wọ́n ṣe ń fi ibẹ̀ sílẹ̀, wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí í bá ara wọn sọ̀rọ̀, pé: “Ọkùnrin yìí ò ṣe nǹkan kan tó yẹ fún ikú tàbí ìdè ẹ̀wọ̀n.”+ 32 Ágírípà wá sọ fún Fẹ́sítọ́ọ̀sì pé: “À bá dá ọkùnrin yìí sílẹ̀ ká ní kò ké gbàjarè sí Késárì.”+

Yorùbá Publications (1987-2026)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2026 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́