ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Mátíù 8:14, 15
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 14 Nígbà tí Jésù wọ ilé Pétérù, ó rí ìyá ìyàwó rẹ̀+ tí àìsàn ibà dá dùbúlẹ̀.+ 15 Ó sì fọwọ́ kan ọwọ́ obìnrin náà,+ ibà náà sì lọ, obìnrin náà wá dìde, ó sì bẹ̀rẹ̀ sí í ṣe ìránṣẹ́ fún un.

  • Mátíù 9:24, 25
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 24 Jésù sọ pé: “Ẹ kúrò níbẹ̀, torí ọmọdébìnrin náà ò kú, ó ń sùn ni.”+ Ni wọ́n bá bẹ̀rẹ̀ sí í rẹ́rìn-ín, wọ́n sì ń fi ṣẹlẹ́yà. 25 Gbàrà tí wọ́n ní kí àwọn èrò náà bọ́ síta, ó wọlé, ó di ọwọ́ ọmọdébìnrin náà mú,+ ọmọ náà sì dìde.+

Yorùbá Publications (1987-2026)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2026 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́