Róòmù 5:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Nítorí ẹ̀ṣẹ̀ ti wà ní ayé kí Òfin tó dé, àmọ́ a kì í ka ẹ̀ṣẹ̀ sí ẹnikẹ́ni lọ́rùn nígbà tí kò sí òfin.+
13 Nítorí ẹ̀ṣẹ̀ ti wà ní ayé kí Òfin tó dé, àmọ́ a kì í ka ẹ̀ṣẹ̀ sí ẹnikẹ́ni lọ́rùn nígbà tí kò sí òfin.+