1 Tẹsalóníkà 1:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 kí ẹ sì lè dúró de Ọmọ rẹ̀ láti ọ̀run,+ ẹni tó gbé dìde kúrò nínú ikú, ìyẹn Jésù tó gbà wá sílẹ̀ kúrò lọ́wọ́ ìrunú tó ń bọ̀.+
10 kí ẹ sì lè dúró de Ọmọ rẹ̀ láti ọ̀run,+ ẹni tó gbé dìde kúrò nínú ikú, ìyẹn Jésù tó gbà wá sílẹ̀ kúrò lọ́wọ́ ìrunú tó ń bọ̀.+